Àwọn Adájọ́ 9:25 BM

25 Àwọn ará ìlú Ṣekemu bá rán àwọn kan ninu wọn, wọ́n lọ ba ní ibùba ní orí òkè de Abimeleki. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí dá gbogbo àwọn tí wọn ń kọjá lọ́nà; ni ìròyìn bá kan Abimeleki.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:25 ni o tọ