45 Abimeleki gbógun ti ìlú náà ní gbogbo ọjọ́ náà, ó gbà á, ó sì pa àwọn eniyan inú rẹ̀; ó wó gbogbo ìlú náà palẹ̀, ó sì da iyọ̀ sí i.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9
Wo Àwọn Adájọ́ 9:45 ni o tọ