Àwọn Adájọ́ 9:5 BM

5 Ó bá lọ sí ilé baba rẹ̀ ní Ofira, ó pa gbogbo aadọrin àwọn arakunrin rẹ̀ lórí òkúta kan, àfi Jotamu àbíkẹ́yìn Gideoni nìkan ni ó ṣẹ́kù, nítorí pé òun sá pamọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:5 ni o tọ