57 Ọlọrun sì mú kí gbogbo ìwà ibi àwọn ará Ṣekemu pada sórí wọn. Èpè tí Jotamu ọmọ Gideoni ṣẹ́ sì ṣẹ mọ́ wọn lára.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9
Wo Àwọn Adájọ́ 9:57 ni o tọ