Ẹkún Jeremaya 1:10 BM

10 Ọ̀tá ti tọwọ́ bọ ilé ìṣúra rẹ̀,wọ́n sì ti kó gbogbo nǹkan iyebíye inú rẹ̀ lọ;ó ń wo àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn,tí wọn ń wọ ibi mímọ́ rẹ̀.Àwọn tí ó pàṣẹ péwọn kò gbọdọ̀ dé àwùjọ àwọn eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:10 ni o tọ