Ẹkún Jeremaya 1:12 BM

12 Ó ní, “Ṣé ọ̀rọ̀ yìí kò kàn yín ni,gbogbo ẹ̀yin tí ẹ̀ ń kọjá lọ?Ẹ̀yin náà ẹ wò ó, kí ẹ ṣe akiyesi rẹ̀,bóyá ìbànújẹ́ kan wàtí ó dàbí èyí tí ó dé bá mi yìí;tí OLUWA mú kí ó dé bá mi,ní ọjọ́ ibinu gbígbóná rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:12 ni o tọ