Ẹkún Jeremaya 2:11 BM

11 Ẹkún sísun ti sọ ojú mi di bàìbàì,ìdààmú bá ọkàn mi;ìbànújẹ́ sì mú kí ó rẹ̀wẹ̀sìnítorí ìparun àwọn eniyan mi,nítorí pé àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ati àwọn ọmọ ọwọ́ ń dákú lójú pópó láàrin ìlú.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:11 ni o tọ