Ẹkún Jeremaya 2:20 BM

20 Wò ó! OLUWA,ṣe akiyesi ohun tí ń ṣẹlẹ̀!Wo àwọn tí ò ń ṣe irú èyí sí!Ṣé ó yẹ kí àwọn obinrin máa jẹ ọmọ wọn?Ọmọ ọwọ́ tí wọn ń tọ́jú!Ṣé ó yẹ kí á pa alufaa ati wolii, ní ibi mímọ́ OLUWA?

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:20 ni o tọ