Ẹkún Jeremaya 2:8 BM

8 OLUWA ti pinnu láti wó odi Sioni lulẹ̀.Ó fi okùn ìwọ̀n wọ̀n ọ́n,kò sì rowọ́ láti parun.Ó jẹ́ kí ilé ìṣọ́ ati odi ìlú wó lulẹ̀ pẹlu ìbànújẹ́,wọ́n sì di àlàpà papọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:8 ni o tọ