Ẹkún Jeremaya 4:10 BM

10 Àwọn obinrin tí wọn ní ojú àánú ti fi ọwọ́ ara wọn se ọmọ wọn jẹ,wọ́n fi ọmọ wọn ṣe oúnjẹ jẹ,nígbà tí ìparun dé bá àwọn eniyan mi.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 4

Wo Ẹkún Jeremaya 4:10 ni o tọ