Ẹkún Jeremaya 4:18 BM

18 Àwọn eniyan ń ṣọ́ ìrìn ẹsẹ̀ wa,tóbẹ́ẹ̀ tí a kò lè rìn gaara ní ìgboro.Ìparun wa súnmọ́lé,ọjọ́ ayé wa ti níye,nítorí ìparun wa ti dé.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 4

Wo Ẹkún Jeremaya 4:18 ni o tọ