Ẹkún Jeremaya 4:20 BM

20 Ẹ̀mí àwa ẹni àmì òróró OLUWA bọ́ sinu kòtò wọn,OLUWA tí à ń sọ nípa rẹ̀ pé,lábẹ́ òjìji rẹ̀ ni a óo máa gbé láàrin àwọn orílẹ̀-èdè.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 4

Wo Ẹkún Jeremaya 4:20 ni o tọ