Ẹkún Jeremaya 4:4 BM

4 Ahọ́n ọmọ ọmú lẹ̀ mọ́ òkè ẹnu rẹ̀ nítorí òùngbẹ.Àwọn ọmọde ń tọrọ oúnjẹ,ṣugbọn kò sí ẹni tí ó fún wọn.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 4

Wo Ẹkún Jeremaya 4:4 ni o tọ