Ẹsita 1:15 BM

15 Ọba bi wọ́n pé, “Gẹ́gẹ́ bí òfin, kí ni kí á ṣe sí Ayaba Faṣiti, nítorí ohun tí ọba pa láṣẹ, tí ó rán àwọn ìwẹ̀fà sí i pé kí ó ṣe kò ṣe é.”

Ka pipe ipin Ẹsita 1

Wo Ẹsita 1:15 ni o tọ