Ẹsita 1:5 BM

5 Lẹ́yìn náà, ọba se àsè ní àgbàlá ààfin fún ọjọ́ meje, fún gbogbo àwọn tí wọ́n wà ní Susa, àtàwọn talaka, àtàwọn eniyan ńláńlá.

Ka pipe ipin Ẹsita 1

Wo Ẹsita 1:5 ni o tọ