Ẹsita 10:2 BM

2 Gbogbo iṣẹ́ agbára ati ipá rẹ̀, ati bí ó ṣe gbé Modekai ga sí ipò ọlá, ni a kọ sinu ìwé ìtàn àwọn ọba Media ati ti Pasia.

Ka pipe ipin Ẹsita 10

Wo Ẹsita 10:2 ni o tọ