Ẹsita 2:1 BM

1 Nígbà tí ó yá, tí ibinu ọba rọlẹ̀, ó ranti ohun tí Faṣiti ṣe, ati àwọn àṣẹ tí òun pa nípa rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹsita 2

Wo Ẹsita 2:1 ni o tọ