11 Lojoojumọ ni Modekai máa ń rìn sókè sódò níwájú àgbàlá ibi tí àwọn ayaba ń gbé, láti bèèrè alaafia Ẹsita, ati bí ó ti ń ṣe sí.
Ka pipe ipin Ẹsita 2
Wo Ẹsita 2:11 ni o tọ