Ẹsita 3:10 BM

10 Ọba bọ́ òrùka àṣẹ tí ó wà ní ọwọ́ rẹ̀, ó fún Hamani, ọmọ Hamedata, ará Agagi, ọ̀tá àwọn Juu.

Ka pipe ipin Ẹsita 3

Wo Ẹsita 3:10 ni o tọ