13 Ṣugbọn gbogbo nǹkan wọnyi kò lè tẹ́ mi lọ́rùn, bí mo bá ń rí Modekai, Juu, tí ó ń jókòó ní ẹnu ọ̀nà ààfin ọba.”
Ka pipe ipin Ẹsita 5
Wo Ẹsita 5:13 ni o tọ