Ẹsita 6:4 BM

4 Ọba bèèrè pé, “Ta ló wà ninu àgbàlá?” Àkókò náà ni Hamani wọ inú àgbàlá ààfin ọba, láti bá ọba sọ̀rọ̀ láti so Modekai rọ̀ sórí igi tí ó rì mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹsita 6

Wo Ẹsita 6:4 ni o tọ