5 Ahasu-erusi ọba bi Ẹsita Ayaba pé, “Ta ni olúwarẹ̀, níbo ni ẹni náà wà, tí ń gbèrò láti dán irú nǹkan bẹ́ẹ̀ wò?”
Ka pipe ipin Ẹsita 7
Wo Ẹsita 7:5 ni o tọ