2 Ọba mú òrùka tí ó gbà lọ́wọ́ Hamani, ó fi bọ Modekai lọ́wọ́. Ẹsita sì fi Modekai ṣe olórí ilé Hamani.
Ka pipe ipin Ẹsita 8
Wo Ẹsita 8:2 ni o tọ