Ẹsita 9:15 BM

15 Ní ọjọ́ kẹrinla oṣù Adari àwọn Juu tí wọ́n wà ní Susa tún parapọ̀, wọ́n sì pa ọọdunrun (300) ọkunrin sí i. Ṣugbọn wọn kò fi ọwọ́ kan ẹrù wọn.

Ka pipe ipin Ẹsita 9

Wo Ẹsita 9:15 ni o tọ