5 Àwọn Juu fi idà pa àwọn ọ̀tá wọn, wọ́n pa wọ́n run. Ohun tí ó wù wọ́n ni wọ́n ṣe sí àwọn tí wọ́n kórìíra wọn.
Ka pipe ipin Ẹsita 9
Wo Ẹsita 9:5 ni o tọ