Ọbadaya 1:21 BM

21 Àwọn olùgbàlà yóo lọ láti Sioni,wọn yóo jọba lórí òkè Edomu;ìjọba náà yóo sì jẹ́ ti OLUWA.”

Ka pipe ipin Ọbadaya 1

Wo Ọbadaya 1:21 ni o tọ