Sakaraya 1:1 BM

1 Ní oṣù kẹjọ, ọdún keji ìjọba Dariusi, OLUWA rán wolii Sakaraya, ọmọ Berekaya, ọmọ Ido, sí àwọn ọmọ Israẹli; ó ní,

Ka pipe ipin Sakaraya 1

Wo Sakaraya 1:1 ni o tọ