Sakaraya 1:21 BM

21 Mo bèèrè pé, “Kí ni àwọn wọnyi ń bọ̀ wá ṣe?”Ó bá dáhùn pé, “Àwọn ìwo wọnyi dúró fún àwọn tí wọ́n fọ́n Juda ká patapata, tóbẹ́ẹ̀ tí kò ku ẹnìkan mọ́. Ṣugbọn àwọn alágbẹ̀dẹ wọnyi wá láti dẹ́rùba àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n fọ́n Juda ká, ati láti fọ́n àwọn náà ká.”

Ka pipe ipin Sakaraya 1

Wo Sakaraya 1:21 ni o tọ