Sakaraya 12:11 BM

11 Ní àkókò náà, ọ̀fọ̀ àwọn ará Jerusalẹmu yóo pọ̀ bí ọ̀fọ̀ tí wọ́n ṣe fún Hadadi Rimoni ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Megido.

Ka pipe ipin Sakaraya 12

Wo Sakaraya 12:11 ni o tọ