Sakaraya 12:5 BM

5 Àwọn ará Juda yóo wá máa sọ láàrin ara wọn pé, ‘OLUWA, àwọn ọmọ ogun ti sọ àwọn ará Jerusalẹmu di alágbára.’

Ka pipe ipin Sakaraya 12

Wo Sakaraya 12:5 ni o tọ