5 Ṣugbọn yóo sọ pé, ‘Èmi kì í ṣe wolii, àgbẹ̀ ni mí; oko ni mò ń ro láti ìgbà èwe mi.’
Ka pipe ipin Sakaraya 13
Wo Sakaraya 13:5 ni o tọ