Sakaraya 14:15 BM

15 Àjàkálẹ̀ àrùn burúkú náà yóo kọlu àwọn ẹṣin, ìbakasíẹ, ràkúnmí, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ati gbogbo àwọn ẹran tí wọ́n bá wà ní ibùdó ogun wọn.

Ka pipe ipin Sakaraya 14

Wo Sakaraya 14:15 ni o tọ