Sakaraya 14:20 BM

20 Tó bá di ìgbà náà, a óo máa kọ “MÍMỌ́ SÍ OLUWA,” sí ara aago tí wọn ń so mọ́ ẹṣin lára. Ìkòkò inú ilé OLUWA, yóo sì máa dàbí àwọn àwo tí ó wà níwájú pẹpẹ.

Ka pipe ipin Sakaraya 14

Wo Sakaraya 14:20 ni o tọ