Sakaraya 14:9 BM

9 OLUWA yóo wá jọba ní gbogbo ayé; Ọlọrun nìkan ni gbogbo aráyé yóo máa sìn nígbà náà, orúkọ kanṣoṣo ni wọn yóo sì mọ̀ ọ́n.

Ka pipe ipin Sakaraya 14

Wo Sakaraya 14:9 ni o tọ