Sakaraya 2:5 BM

5 Èmi fúnra mi ni n óo jẹ́ odi iná tí n óo yí i ká, tí n óo máa dáàbò bò ó, n óo sì fi ògo mi kún inú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Sakaraya 2

Wo Sakaraya 2:5 ni o tọ