Sakaraya 8:22 BM

22 Ọpọlọpọ eniyan ati àwọn orílẹ̀-èdè ńlá yóo wá sin OLUWA àwọn ọmọ ogun, wọn óo sì wá wá ojurere rẹ̀ ní Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Sakaraya 8

Wo Sakaraya 8:22 ni o tọ