Filipi 1:13 BM

13 Ó ti wá hàn sí gbogbo àwọn tí ó wà ní ààfin ati gbogbo àwọn eniyan yòókù pé nítorí ti Kristi ni mo ṣe wà ninu ẹ̀wọ̀n.

Ka pipe ipin Filipi 1

Wo Filipi 1:13 ni o tọ