Filipi 1:14 BM

14 Èyí fún ọpọlọpọ ninu àwọn onigbagbọ tí wọ́n mọ ìdí tí mo fi wà ninu ẹ̀wọ̀n ní ìgboyà gidigidi láti máa waasu ìyìn rere láì bẹ̀rù.

Ka pipe ipin Filipi 1

Wo Filipi 1:14 ni o tọ