Galatia 1:15 BM

15 Ṣugbọn nígbà tí ó wu Ọlọrun, tí ó ti yà mí sọ́tọ̀ láti inú ìyá mi, ó fi oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ pè mí,

Ka pipe ipin Galatia 1

Wo Galatia 1:15 ni o tọ