Galatia 2:13 BM

13 Àwọn Juu yòókù bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àgàbàgebè pẹlu Peteru. Wọ́n tilẹ̀ mú Banaba pàápàá wọ ẹgbẹ́ àgàbàgebè wọn!

Ka pipe ipin Galatia 2

Wo Galatia 2:13 ni o tọ