Galatia 2:18 BM

18 Nítorí bí ó bá jẹ́ pé àwọn ohun tí mo ti wó lulẹ̀ ni mo tún ń kọ́, èmi náà di ẹlẹ́ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Galatia 2

Wo Galatia 2:18 ni o tọ