Galatia 2:5 BM

5 Ṣugbọn a kò fi ìgbà kankan gbà wọ́n láyè rárá, kí ó má dàbí ẹni pé ọ̀rọ̀ tiwọn ni ó borí, kí òtítọ́ ìyìn rere lè wà pẹlu yín.

Ka pipe ipin Galatia 2

Wo Galatia 2:5 ni o tọ