Galatia 4:29 BM

29 Ṣugbọn bí ó ti rí látijọ́, tí ọmọ tí a bí nípa ìfẹ́ ara ń ṣe inúnibíni ọmọ tí a bí nípa Ẹ̀mí, bẹ́ẹ̀ náà ni ó wà títí di ìsinsìnyìí.

Ka pipe ipin Galatia 4

Wo Galatia 4:29 ni o tọ