Galatia 6:17 BM

17 Láti ìgbà yìí lọ, kí ẹnikẹ́ni má ṣe yọ mí lẹ́nu mọ́, nítorí ojú pàṣán wà ní ara mi tí ó fihàn pé ti Jesu ni mí.

Ka pipe ipin Galatia 6

Wo Galatia 6:17 ni o tọ