Jakọbu 2:1 BM

1 Ẹ̀yin ará mi, níwọ̀n ìgbà tí ẹ ní igbagbọ ninu Oluwa wa, Jesu Kristi, Oluwa tí ó lógo, ẹ má máa ṣe ojuṣaaju.

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:1 ni o tọ