Jakọbu 2:2 BM

2 Bí àpẹẹrẹ, bí ẹnìkan bá wọ àwùjọ yín, tí ó fi òrùka wúrà sọ́wọ́, tí ó wọ aṣọ tí ń dán, tí talaka kan náà bá wọlé tí ó wọ aṣọ tí ó dọ̀tí;

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:2 ni o tọ