Jakọbu 2:11 BM

11 Nítorí ẹnìkan náà tí ó wí pé, “Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe àgbèrè,” òun náà ni ó wí pé, “Ìwọ kò gbọdọ̀ paniyan.” Bí o kò bá ṣe àgbèrè ṣugbọn o paniyan, o ti di arúfin.

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:11 ni o tọ