Jakọbu 2:10 BM

10 Nítorí ẹni tí ó bá pa gbogbo òfin mọ́, ṣugbọn tí ó rú ẹyọ kan ṣoṣo, ó jẹ̀bi gbogbo òfin.

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:10 ni o tọ