Johanu 10:24 BM

24 Àwọn Juu bá pagbo yí i ká, wọ́n sọ fún un pé, “Nígbà wo ni ìwọ yóo tó fi ọkàn wa balẹ̀? Bí ìwọ bá ni Mesaya, sọ fún wa pàtó.”

Ka pipe ipin Johanu 10

Wo Johanu 10:24 ni o tọ