29 Ohun tí Baba mi ti fún mi tóbi ju ohun gbogbo lọ. Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè já a gbà mọ́ Baba mi lọ́wọ́.
Ka pipe ipin Johanu 10
Wo Johanu 10:29 ni o tọ